| Hustle everyday and night |
| Pray make them no stain my white |
| Even when I go all the way (Still many people go backbite) |
| The future bright |
| Every likkle thing would be alright |
| You can never know who is who (Pray make Oluwa dey my side) |
|
| Mo pe Alpha ati Omega |
| Afi ko dide ja |
| Afi ko ṣaanu mi |
| Afi ko ja fun mi |
| Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi |
| Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni |
| Ko yẹ ko maa lọ bee |
| Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ |
|
| Iya ati Baba Lọla lo bi mi ṣugbọn mo tunra mi bi |
| Ẹlẹdaa mi fẹ sun mo dabara bo o ko ji |
| Darukọ iṣẹ jamajama kan ti mi o ṣe ri |
| Mo gbe pọnnpọ pa sẹ diẹ lo ku sẹ ki igun mi pa lori |
| Baba pastor o tete mọ pe Zanku n fo window lo si show, dagboru pẹlu kito |
| Femi Brookeey lo kọkọ mu mi lọ si studio |
| Orin were mo kọ ju, awọn temi lo dun bi kopiko |
| Mi o le gbagbe awọn nigga mi, awọn l'ọn ginger mi |
| Ti n ba wa owo studio ti wọn a towo bapo knicker mi |
| Ten toes on my grind nisin mo dọmọ to sabi |
| Up Agbede ni Ikorodu awọn temi l'Onigari |
|
| That time! |
| Oh my Lordy wọn ni ko le lọ far |
| Wọn ni bawo lẹni ti o niṣẹ ṣe ma san tithes (Awọn bastard) |
| Bi orukọ ọmọ mi Toluwalaṣẹ |
| Unstoppable bo wun wọn k'ọn gbajẹ |
|
| Mo pe Alpha ati Omega |
| Afi ko dide ja |
| Afi ko ṣaanu mi |
| Afi ko ja fun mi |
| Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi |
| Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni |
| Ko yẹ ko maa lọ bee |
| Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ |
|
| Mo pada dọmọ t'ọn fi n yangan |
| Ọmọ t'ọn fi n tọrọ, irọ o da ma mẹnu le ọmọ jọmọ lọ |
| Pain in the ass ti o common fun awọn doubting Thomas |
| Eewo ti mu wọn lẹnu aje wọn le sọrọ mọ |
| I go dey always remember |
| When I wan cook but gas no dey cylinder |
| I was born to do wonders |
| But ogun idile no wan gimme chance |
| Never you say never! |
| My life story na big ginger |
| 'Symbol of Hope', e dey play, e dey choke |
| Steady motivation fawọn temi ninu hole |
|
| Mo pe Alpha ati Omega |
| Afi ko dide ja |
| Afi ko ṣaanu mi |
| Afi ko ja fun mi |
| Awọn l'ọn fẹ yọ bumper mi |
| Awọn l'ọn tun p'ọlọpa ni |
| Ko yẹ ko maa lọ bee |
| Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ |
|
| Ko yẹ ko maa lọ bee |
| Ko dẹ yẹ ko maa lọ bẹẹ |
|